BeatByte

Loading...

Home / Ayo Maff /

7 Days

7 DAYS

By

Ayo Maff


Emi ọmọ oro
I no fit pass my lane
Wọn ni ki n ma jade
But wọn le mi
Emi ọmọ owo
I no do pass myself
Wọn ni ki n ma sare
But wọn le mi
So I cannot see my brother Ojo
And popo them don lock my brother up o
Say make them free my brothers oh-oh
Them no kill person
Them be ọmọ owo o
Aje ogugulusọ o
Haaa o kuku ni sọ fun mi
Haaa o kuku ni sọ fun mi
Mo mọ pe o kuku ni sọ fun mi

Gbogbo owo ti mo na
Fun ọjọ meje
Mo wẹṣẹ dudu
K'ọjọ to lọ o
Gbogbo owo ti mo na
Fun ọjọ meje
Mo wẹṣẹ dudu
Ọjọ le lọ o

Ah ki iku ma pa alanu mi
Kọta mi le riran wo
Kọta mi le riran wo
Ah ki iku ma pa alanu wa
Kọta wa le riran wo
Kọta wa le riran wo

Ah ki iku ma pa alanu mi
Kọta mi le riran wo
Kọta mi le riran wo
Ah ki iku ma pa alanu wa
Kọta wa le riran wo
Kọta wa le riran wo

I've been thinking
I've been too deep in my feelings
Bless my pocket
Ṣe mi lọmọ t'ọn ma ji ri
If I no hustle
Who go take care of my siblings
If I no hustle
Who go take care of my siblings
Mo sare wọ Jerusalem
Mo gbadura ki n le pawo
If ọlọpaa no lock Ojo up
My brother he dey yawo
Man make man kala
Ẹjẹ loju mi
Man make man kala ah
Ẹjẹ lo u mi

Gbogbo owo ti mo na
Fun ọjọ meje
Mo wẹṣẹ dudu
K'ọjọ to lọ o
Gbogbo owo ti mo na
Fun ọjọ meje
Mo wẹṣẹ dudu
Ọjọ le lọ o

Ah ki iku ma pa alanu mi
Kọta mi le riran wo
Kọta mi le riran wo
Ah ki iku ma pa alanu wa
Kọta wa le riran wo
Kọta wa le riran wo

Other Lyrics by Ayo Maff

Jama Jama

Saturday Night

Light Up

2 Dollar

Find Money

Are You There?

7 Days

Go Back

A Beautiful Song

Panic

Street Anthem

Another Day

Last Week

Jama Jama (Remix)

7 Lives

Dealer

8 Days

Journey

Songs Featuring Ayo Maff

No songs found for the featured artist: Ayo Maff

Most Viewed Lyrics